1 Ẹ funpe naa kikan, 2. Fun 'pe t'Ọdaguntan;
Ipe ihinrere, T'a ti pa s'etutu,
K'o dun jake jado, Jẹ ki agbayé mọ,
L'eti gbogbo ẹda: Agbara ẹjẹ Rẹ,
Egbe:Ọdun idasilẹ ti de; Egbe: Ọdun idasilẹ... etc.
Pada
ẹlẹsẹ pada.
3. Ẹyin ẹru ẹsẹ, 4. Olori Alufa,
Ẹ so'ra yin d'ọmọ, L'Olugbala ise;
Lọwọ Kristi Jesu, O fi 'ra Rẹ rubọ
Ẹ gb'ominira yin. Arukun, aruda.
Egbe:Ọdun idasilẹ..etc. Egbe: Ọdun
idasilẹ... etc.
5. Ọkan alarẹ, wa,
Sinmi laya Jesu,
Onirobinujẹ,
Tujuka, si ma yọ.
Egbe:Ọdun idasilẹ...........etc.
No comments:
Post a Comment