1.
“HOSANNA
s'ọmọ Dafidi”, 2. “Hosanna s'ọmọ Dafidi',
Hosanna, ẹ kọrin L'Ẹgbẹ Angẹli n ke;
“Olubukun
l'Ẹni ti mbọ, Gbogbo ẹda jumọ gberin,
L'orukọ
Oluwa.” Hosanna s'Ọba wa.
3. Hosanna! awọn Heberu, 4. T'agba t'ewe n
ke Hosanna!
Ja im'ọpẹ sọna, K'ijiya Rẹ to de;
Hosanna a mu ẹbun wa, Loni, a si n kọ Hosanna!
Fi tun ọna Rẹ se. B'o ti n jọba l'oke
5. B'O ti gba 'yin wọn nigba naa
Jọ gba ẹbẹ wa yi,
Lọrun ka le b'angẹl' kọrin,
Hosanna s'Ọba wa.
No comments:
Post a Comment