1. JESU
lorukọ to ga ju, 2 Kérúbù ati Séráfù,
Layé a ti lọrun; Wọn yi 'tẹ Baba ka,
Awọn Angẹli wolẹ fun, Nigba gbogbo niwaju Rẹ,
Esu, bẹru o sa. Wọn ń kọ orin iyin.
Egbe:Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ, Egbe:Ha!
Ko s'ariyanjiyan mọ,.etc.
Ipe
miiran ko si,
O daju wi pé
Jesu ku,
Ani f'emi
ẹlẹsẹ
3. Olugbala
sẹgun iku, 4. Kérúbù ati Séráfù,
Ijọba Satan fọ; Ẹ fẹran ara yin;
Gbogbo ẹda ẹ bu sayọ, Ifẹ ni awọn Angẹli,
Ka yin Baba logo. Fi ń sin Baba lok
Egbe:Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,.....etc. Egbe: Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,.etc.
Egbe:Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,.....etc. Egbe: Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,.etc.
5. Jesu,
Olori Ijọ wa, 6. Jehovah Jire Ọba wa,
Bukun wa layé wa; Iyin f'orukọ Rẹ;
Jọwọ pese fun aini wa, Ma jẹ ki oso at'ajẹ
K'ebi alẹ ma pa wa. Ri wa lọjọ ayé wa.
Egbe:Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,.....etc. Egbe:Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,.etc.
7. Jesu,
fọ itẹgun esu,
Iwọ l'Ọba Ogo;
Iyin, ope ni fun Baba,
Ni fun Mẹtalọkan.
Egbe:Ha! Ko s'ariyanjiyan mọ,
Ipe
miran ko si,
O daju wi pé
Jesu ku,
Ani f' emi
ẹlẹsẹ.
No comments:
Post a Comment